Wt/yo/abo

From Wikimedia Incubator
< Wt‎ | yo
Wt > yo > abo

Yorùbá[edit | edit source]

Ọ̀rọ̀ orúkọ[edit | edit source]

Abo jẹ́ ọ̀rọ̀-orúkọ [1] fún ohun abẹ̀mí bí ọmọ ènìyàn ẹranko kòkòrò tabí ohun aláìlẹ́mú tí ó ní àwòmọ́ ìṣesí obìnrin tí ó lè lóyún, tọ́ ọmọ, tabí tí ó lè gba ìbáṣepọ̀ alààyè láti ọ̀dọ̀ akọ tàbí ọkùnrin.


Àpẹẹrẹ: Orúkọ Ìyá Abo ni adìyẹ tí mo rà wálé. Ewúrẹ́ mi bí ọmọ méjì tí wọ́n jẹ́ abo

Ní èdè míràn[edit | edit source]

Èdè Gẹ̀ẹ́sì[edit | edit source]

Àwọn ìtọ́kasí[edit | edit source]

Template:Wt/yo/reflist

  1. Template:Wt/yo/cite web