Jump to content

Wt/yo/Orí

From Wikimedia Incubator
< Wt | yo
Wt > yo > Orí
Head lateral sagittal brain

Orí[1] jẹ́ ìkan pàtàkì lára ẹ̀yà ara ènìyàn tàbí ẹranko tí ó so mọ́ ọrùn tí ó ń ṣe àkóso gbogbo ẹ̀yà ara t'ókù. Lára orí ni a ti rí àwọn ẹ̀yà ara míìràn tí wọ́n ṣe pàtàkì nínú ayé ẹ̀dá tí a lè f'ojú rí bí irun-orí, ìpéǹpéjú, ojú, etí, ètè, ẹnu, àrùngbọn]] àti irun àrùngbọn. Àwọn ẹ̀yà ara tí a kò lè f'ojú rí ní ìta gbangba ti wọ́n wà nínú orí ni ọpọlọ, eyín, ahọ́n, itọ́, ikun àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. [2]

Àwọn ìtọkasí

[edit | edit source]
  1. Template:Wt/yo/cite web
  2. Template:Wt/yo/cite web