Wt/yo/Ìyá
Appearance
Yorùbá
[edit | edit source]Ọ̀rọ̀ orúkọ
[edit | edit source]Ìyá jẹ́ ọ̀rọ̀-orúkọ [1] ẹni tí a fi ń pe ẹni tí ó jẹ́ abo tàbí obìnrin
Ìyá jẹ́ obìnrin tí ó fẹ́ ọkùnrin tí ó sì tún gbà láti máa jẹ́ aya fún akọ títí láé nígbà tí ó sì tún jẹ́ ìyá fún awọn ọmọ tí obìnrin bá bí fún ọkọ rẹ̀. Àpẹẹrẹ: Orúkọ Ìyá Ọlálónpé